Torí Mo Ti Gbàgbọ́...

Torí mo ti gbàgbọ́ nínú Jésù,
Ó ti gbà mí lọ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ àti èṣù,
Kúrò ní ọwọ́ aládé aráyé,
Kí èmí kó lè jọba ní gbogbo àgbáyé.

Èsù, ẹ̀ṣẹ̀ àti ọmọlẹ́yìn rẹ̀,
Ikú nìkan ni yóò parí gbogbọ rẹ̀,
Ẹ di Jésù mú, ẹ má ṣe fi sílẹ̀,
Nítorí ọ̀run mà ni èrè rẹ̀. 

Jésù wá láti kú fún wa nínú ayé,
Nítorí kì àwa kí ó lè yè,
Ẹ má ṣe kó ayé àti ẹ̀kún rẹ̀,
Torí ẹkún rere ayọ̀ parí gbogbọ rẹ̀.

Jésù ń pé ẹlẹ́ṣẹ̀ sí ọ̀dọ̀,
Àwọn ọmọdé, àgbà àti ọ̀dọ́,
Ó ń pè wọ́n wá láti ní ìyè,
Kí wọn má báà ṣègbé nínú ayé.


In English, it reads...
Because I now believe in Jesus, 
He has saved me from sin and the devil,
Away from the hands of the prince of this world,
In order for me to reign over all the earth.

The devil, sin and its accomplice,
Death is the end of it all,
Hold on to Jesus and never leave Him alone,
Because Heaven is the reward.

Jesus came to this world to die for us,
In order for us to be saved,
Do not reject His life and it's fullness,
Because fullness of joy abounds at the end of it all.

Jesus is calling the sinners unto Him,
The children, adults and the youths,
He's calling them to come and have life,
In order for them not to perish in this world. 


The thing about this poem is that it came as a song... Later, I'll sing it, maybe when we have a 

I guess you got the message... Don't forget to tell someone about the goodness of God today!

2 تعليقات

إرسال تعليق

Post a Comment

أحدث أقدم

© 2021 NELOC Media Rights Reserved